Saturday 30 July 2022

Adura fun Iwosan kuro ninu aileya Prayers for healing from Infirmities

SHARE



Ailera kii se ife olorun fun aye awa omo re. Ilera to peye ni ife olorun seto fun wa

Isaiah  Ori Ketale laadota, ese karun so wipe

“Ṣùgbọ́n won saa lọgbẹ́ nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wa, a pa á lára ​​nítorí aise dede wa; Ìjìyà àlàáfíà wa ń bẹ lára ​​Rẹ̀, Àti nípa ìnà Rẹ̀, a mú wa láradá.”




SHARE

Author: verified_user

0 comments:

Kindly comment here!